0:00/???
  1. Ore Jesu

From the recording Ore Jesu

Lyrics

Yeah, Oh Oh

Kini ma fi san fun ore Jesu
Kini ma fi san fun ore Baba mi o
Kini ma fi san fun ore Jesu
Kini ma fi san fun ore re

Se bi ‘wo lo ni gbo gbo orun o
Se bi ‘wo lo ni gbo gbo aye
Egberun ahon ko to fun yin o o Baba
Fun gbo gbo ore t’o se

Kini ma fi san fun ore Jesu
Kini ma fi san fun ore Baba mi o
Kini ma fi san fun ore Jesu
Kini ma fi san fun ore re

Opolopo lo ti ku
Opolopo lo ti lo o
But it’s in You I live an d move and have my being
Eh Baba
You’re too much o

Kini ma fi san fun ore Jesu
Kini ma fi san fun ore Baba mi o
Kini ma fi san fun ore Jesu, eba mi yo
Kini ma fi san fun ore re

Se bi ‘wo lo ni gbo gbo orun o
Se bi ‘wo lo ni gbo gbo aye
Egberun ahon ko to fun yin o o
Fun gbo gbo ore t’o se

Kini ma fi san fun ore Jesu
Kini ma fi san fun ore Baba mi o
Kini ma fi san fun ore Jesu, eba mi yo
Kini ma fi san fun ore re

Se bi ‘wo lo ni gbo gbo orun o
Se bi ‘wo lo ni gbo gbo aye
Egberun ahon ko to fun yin o o
Fun gbo gbo ore t’o se

Kini ma fi san fun ore Jesu
Kini ma fi san fun ore Baba mi o
Kini ma fi san fun ore Jesu, eba mi yo
Kini ma fi san fun ore re